-
Nọ́ńbà 23:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ṣé kí n wá lọ gégùn-ún fún àwọn tí Ọlọ́run ò fi gégùn-ún ni?
Àbí kí n lọ dẹ́bi fún àwọn tí Jèhófà kò dá lẹ́bi?+
-
-
Nọ́ńbà 24:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Inú wá bí Bálákì sí Báláámù gan-an. Bálákì wá fi ìbínú pàtẹ́wọ́, ó sì sọ fún Báláámù pé: “Torí kí o lè gégùn-ún fún àwọn ọ̀tá mi ni mo ṣe pè ọ́ + wá, àmọ́ ṣe lo kàn ń súre fún wọn lẹ́ẹ̀mẹta yìí.
-