Nehemáyà 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí Sáńbálátì, Tòbáyà,+ àwọn ọmọ ilẹ̀ Arébíà+ àti àwọn ọmọ Ámónì pẹ̀lú àwọn ará Áṣídódì+ gbọ́ pé àtúnṣe ògiri Jerúsálẹ́mù ń lọ déédéé àti pé a ti ń dí àwọn àlàfo rẹ̀, inú bí wọn gidigidi.
7 Nígbà tí Sáńbálátì, Tòbáyà,+ àwọn ọmọ ilẹ̀ Arébíà+ àti àwọn ọmọ Ámónì pẹ̀lú àwọn ará Áṣídódì+ gbọ́ pé àtúnṣe ògiri Jerúsálẹ́mù ń lọ déédéé àti pé a ti ń dí àwọn àlàfo rẹ̀, inú bí wọn gidigidi.