Nọ́ńbà 35:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ìlú tí wọ́n á máa gbé látinú ogún tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa gbà,+ kí wọ́n sì fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ibi ìjẹko tó yí àwọn ìlú+ náà ká.
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ìlú tí wọ́n á máa gbé látinú ogún tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa gbà,+ kí wọ́n sì fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ibi ìjẹko tó yí àwọn ìlú+ náà ká.