Nehemáyà 10:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 A tún ṣẹ́ kèké lórí bí àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì àti àwọn èèyàn náà á ṣe máa mú igi wá sí ilé Ọlọ́run wa, ní agboolé-agboolé àwọn bàbá wa, ní àkókò tí a yàn lọ́dọọdún, láti máa fi dáná lórí pẹpẹ Jèhófà Ọlọ́run wa, bó ṣe wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin.+
34 A tún ṣẹ́ kèké lórí bí àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì àti àwọn èèyàn náà á ṣe máa mú igi wá sí ilé Ọlọ́run wa, ní agboolé-agboolé àwọn bàbá wa, ní àkókò tí a yàn lọ́dọọdún, láti máa fi dáná lórí pẹpẹ Jèhófà Ọlọ́run wa, bó ṣe wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin.+