Nehemáyà 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mo gba Ẹnubodè Àfonífojì+ jáde ní òru, mo kọjá níwájú Ojúsun Ejò Ńlá lọ sí Ẹnubodè Òkìtì Eérú,+ mo sì ṣàyẹ̀wò àwọn ògiri Jerúsálẹ́mù tó ti wó lulẹ̀ àti àwọn ẹnubodè rẹ̀ tí iná ti jó.+
13 Mo gba Ẹnubodè Àfonífojì+ jáde ní òru, mo kọjá níwájú Ojúsun Ejò Ńlá lọ sí Ẹnubodè Òkìtì Eérú,+ mo sì ṣàyẹ̀wò àwọn ògiri Jerúsálẹ́mù tó ti wó lulẹ̀ àti àwọn ẹnubodè rẹ̀ tí iná ti jó.+