Jeremáyà 39:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbà tí Sedekáyà ọba Júdà àti gbogbo ọmọ ogun rí wọn, wọ́n fẹsẹ̀ fẹ,+ wọ́n gba ọ̀nà ọgbà ọba jáde kúrò nínú ìlú náà lóru, wọ́n gba ẹnubodè tó wà láàárín ògiri oníbejì kọjá, wọ́n sì gba ọ̀nà Árábà jáde.+
4 Nígbà tí Sedekáyà ọba Júdà àti gbogbo ọmọ ogun rí wọn, wọ́n fẹsẹ̀ fẹ,+ wọ́n gba ọ̀nà ọgbà ọba jáde kúrò nínú ìlú náà lóru, wọ́n gba ẹnubodè tó wà láàárín ògiri oníbejì kọjá, wọ́n sì gba ọ̀nà Árábà jáde.+