Nehemáyà 12:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Wọ́n dé Ẹnubodè Ojúsun,+ wọ́n sì lọ tààrà sórí Àtẹ̀gùn+ Ìlú Dáfídì+ níbi ìgòkè ògiri lórí Ilé Dáfídì títí lọ dé Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn.
37 Wọ́n dé Ẹnubodè Ojúsun,+ wọ́n sì lọ tààrà sórí Àtẹ̀gùn+ Ìlú Dáfídì+ níbi ìgòkè ògiri lórí Ilé Dáfídì títí lọ dé Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn.