-
1 Àwọn Ọba 2:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Lẹ́yìn náà, Dáfídì sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín sí Ìlú Dáfídì.+
-
-
2 Kíróníkà 16:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Níkẹyìn, Ásà sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀;+ ó kú ní ọdún kọkànlélógójì ìjọba rẹ̀. 14 Nítorí náà, wọ́n sin ín sí ibi ìsìnkú rẹ̀ tó lọ́lá, èyí tó gbẹ́ fún ara rẹ̀ sí Ìlú Dáfídì;+ wọ́n sì tẹ́ ẹ sórí àga ìgbókùú tí wọ́n ti fi òróró básámù sí lára àti oríṣiríṣi èròjà tí a pò mọ́ àkànṣe òróró ìpara.+ Síwájú sí i, wọ́n ṣe ìfinásun* tó ṣàrà ọ̀tọ̀ nítorí rẹ̀ nígbà ìsìnkú rẹ̀.
-