Nehemáyà 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ésérì ọmọ Jéṣúà+ tó jẹ́ olórí ní Mísípà ṣe àtúnṣe ẹ̀ka míì ní apá tó tẹ̀ lé e níwájú ìgòkè tó lọ sí Ilé Ìhámọ́ra Níbi Ìtì Ògiri.+
19 Ésérì ọmọ Jéṣúà+ tó jẹ́ olórí ní Mísípà ṣe àtúnṣe ẹ̀ka míì ní apá tó tẹ̀ lé e níwájú ìgòkè tó lọ sí Ilé Ìhámọ́ra Níbi Ìtì Ògiri.+