-
Sáàmù 149:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Kí orin ìyìn Ọlọ́run wà lẹ́nu wọn,
Kí idà olójú méjì sì wà lọ́wọ́ wọn,
7 Láti gbẹ̀san lára àwọn orílẹ̀-èdè,
Kí wọ́n sì fìyà jẹ àwọn èèyàn,
-