Ẹ́sítà 9:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Bákan náà, ìyókù àwọn Júù tó wà ní àwọn ìpínlẹ̀ abẹ́ àṣẹ ọba kóra jọ, wọ́n sì gbèjà ara* wọn.+ Wọ́n rẹ́yìn àwọn ọ̀tá wọn,+ ẹgbẹ̀rún márùnléláàádọ́rin (75,000) lára àwọn tó kórìíra wọn ni wọ́n pa; àmọ́ wọn ò kó ohun ìní èyíkéyìí.
16 Bákan náà, ìyókù àwọn Júù tó wà ní àwọn ìpínlẹ̀ abẹ́ àṣẹ ọba kóra jọ, wọ́n sì gbèjà ara* wọn.+ Wọ́n rẹ́yìn àwọn ọ̀tá wọn,+ ẹgbẹ̀rún márùnléláàádọ́rin (75,000) lára àwọn tó kórìíra wọn ni wọ́n pa; àmọ́ wọn ò kó ohun ìní èyíkéyìí.