Ẹ́sítà 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà tó kan Ẹ́sítà ọmọ Ábíháílì arákùnrin òbí Módékáì, ẹni tó mú un ṣe ọmọ,+ láti wọlé lọ bá ọba, kò béèrè ohunkóhun lẹ́yìn ohun tí Hégáì ìwẹ̀fà ọba, olùtọ́jú àwọn obìnrin, fún un. (Ní gbogbo àkókò yìí, Ẹ́sítà ń rí ojú rere gbogbo àwọn tó rí i).
15 Nígbà tó kan Ẹ́sítà ọmọ Ábíháílì arákùnrin òbí Módékáì, ẹni tó mú un ṣe ọmọ,+ láti wọlé lọ bá ọba, kò béèrè ohunkóhun lẹ́yìn ohun tí Hégáì ìwẹ̀fà ọba, olùtọ́jú àwọn obìnrin, fún un. (Ní gbogbo àkókò yìí, Ẹ́sítà ń rí ojú rere gbogbo àwọn tó rí i).