-
Ẹ́sítà 9:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 àwọn Júù sọ ọ́ di dandan fún ara wọn àti fún àtọmọdọ́mọ wọn pẹ̀lú gbogbo àwọn tó dara pọ̀ mọ́ wọn+ láti máa ṣe ayẹyẹ ọjọ́ méjèèjì yìí láìjẹ́ kó yẹ̀, kí wọ́n sì máa ṣe ohun tó wà lákọsílẹ̀ nípa àwọn ọjọ́ náà ní àkókò tí wọ́n bọ́ sí lọ́dọọdún.
-