3 ní ọdún kẹta ìjọba rẹ̀, ó se àsè ńlá fún gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Àwọn ọmọ ogun Páṣíà+ àti Mídíà,+ àwọn èèyàn pàtàkì àti àwọn olórí ìpínlẹ̀* wà níwájú rẹ̀,
15 Níkẹyìn, àwọn ọkùnrin yẹn jọ lọ sọ́dọ̀ ọba, wọ́n sì sọ fún ọba pé: “Ọba, rántí pé òfin àwọn ará Mídíà àti Páṣíà ni pé ìfòfindè tàbí àṣẹ èyíkéyìí tí ọba bá gbé kalẹ̀ kò ṣeé yí pa dà.”+