ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sítà 3:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ ọba tó wà ní ẹnubodè ọba máa ń tẹrí ba fún Hámánì, wọ́n sì ń wólẹ̀ fún un, nítorí ohun tí ọba pàṣẹ pé kí wọ́n máa ṣe fún un nìyẹn. Àmọ́ Módékáì kọ̀, kò tẹrí ba fún un, kò sì wólẹ̀.

  • Ẹ́sítà 10:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Módékáì tó jẹ́ Júù ni igbá kejì Ọba Ahasuérúsì. Ẹni ńlá ni* láàárín àwọn Júù, gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ ló sì ń bọ̀wọ̀ fún un, ó ń ṣiṣẹ́ fún ire àwọn èèyàn rẹ̀, ó sì ń jà fún ire* gbogbo àtọmọdọ́mọ wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́