- 
	                        
            
            Ẹ́sítà 1:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        12 Ṣùgbọ́n Fáṣítì Ayaba kọ̀, kò wá ní gbogbo ìgbà tí àwọn òṣìṣẹ́ ààfin wá jíṣẹ́ ọba fún un. Nítorí náà, inú bí ọba gidigidi, ó sì gbaná jẹ. 
 
-