-
Ẹ́sítà 1:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 àwọn tó sún mọ́ ọn jù lọ ni Káṣénà, Ṣétárì, Ádímátà, Táṣíṣì, Mérésì, Másénà àti Mémúkánì, àwọn ìjòyè méje+ láti Páṣíà àti Mídíà, tí wọ́n máa ń wá sọ́dọ̀ ọba, tí wọ́n sì wà ní ipò tó ga jù nínú ìjọba náà).
-