Ẹ́sítà 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Tó bá dáa lójú ọba, kí ó pa àṣẹ kan, kí wọ́n sì kọ ọ́ sílẹ̀ pé kí a pa wọ́n run. Màá fún àwọn òṣìṣẹ́ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) tálẹ́ńtì* fàdákà pé kí wọ́n kó o sínú ibi ìṣúra ọba.”*
9 Tó bá dáa lójú ọba, kí ó pa àṣẹ kan, kí wọ́n sì kọ ọ́ sílẹ̀ pé kí a pa wọ́n run. Màá fún àwọn òṣìṣẹ́ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) tálẹ́ńtì* fàdákà pé kí wọ́n kó o sínú ibi ìṣúra ọba.”*