-
Ẹ́sítà 3:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Kí wọ́n fi ẹ̀dà lẹ́tà náà ṣe òfin fún ìpínlẹ̀* kọ̀ọ̀kan, kí wọ́n sì kéde rẹ̀ fún gbogbo èèyàn, kí wọ́n lè múra sílẹ̀ de ọjọ́ náà. 15 Àwọn asáréjíṣẹ́ náà jáde lọ kíákíá+ bí ọba ṣe pa á láṣẹ; wọ́n gbé òfin náà jáde ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.* Ọba àti Hámánì wá jókòó láti mutí, àmọ́ ìlú Ṣúṣánì* wà nínú ìdàrúdàpọ̀.
-