Ẹ́sítà 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ́sítà kò sọ nǹkan kan nípa àwọn ìbátan rẹ̀ àti àwọn èèyàn rẹ̀,+ bí Módékáì ṣe pa á láṣẹ fún un; Ẹ́sítà ń ṣe ohun tí Módékáì sọ, bí ìgbà tó ṣì wà lábẹ́ àbójútó rẹ̀.+
20 Ẹ́sítà kò sọ nǹkan kan nípa àwọn ìbátan rẹ̀ àti àwọn èèyàn rẹ̀,+ bí Módékáì ṣe pa á láṣẹ fún un; Ẹ́sítà ń ṣe ohun tí Módékáì sọ, bí ìgbà tó ṣì wà lábẹ́ àbójútó rẹ̀.+