-
Ẹ́sítà 5:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Torí náà, ọba sọ fún àwọn ọkùnrin rẹ̀ pé: “Ẹ sọ fún Hámánì pé kó wá kíákíá, gẹ́gẹ́ bí Ẹ́sítà ṣe sọ.” Ọba àti Hámánì sì lọ síbi àsè tí Ẹ́sítà sè.
-