-
Ẹ́sítà 5:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Tí mo bá rí ojú rere ọba, tó bá sì wu ọba láti ṣe ohun tí mo fẹ́, kó sì fún mi ní ohun tí mo béèrè, kí ọba àti Hámánì wá síbi àsè tí màá sè fún wọn lọ́la; ọ̀la ni màá sì béèrè ohun tí ọba ní kí n béèrè.”
-