-
Jóòbù 15:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Màá sọ fún ọ; fetí sí mi!
Màá ròyìn ohun tí mo rí,
18 Ohun tí àwọn amòye ròyìn, bí wọ́n ṣe gbọ́ ọ lẹ́nu àwọn bàbá wọn,+
Àwọn ohun tí wọn ò fi pa mọ́.
-