Jóòbù 20:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Pé igbe ayọ̀ ẹni burúkú kì í pẹ́Àti pé ìgbà díẹ̀ ni inú ẹni tí kò mọ Ọlọ́run* fi máa ń dùn.+