Diutarónómì 32:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+ Sáàmù 143:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 143 Jèhófà, gbọ́ àdúrà mi;+Gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún ìrànlọ́wọ́. Dá mi lóhùn nínú òtítọ́ rẹ àti òdodo rẹ. 2 Má ṣe bá ìránṣẹ́ rẹ ṣẹjọ́,Nítorí kò sí alààyè kankan tó lè jẹ́ olódodo níwájú rẹ.+ Róòmù 3:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Torí gbogbo èèyàn ti ṣẹ̀, wọn ò sì kúnjú ìwọ̀n ògo Ọlọ́run,+
4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+
143 Jèhófà, gbọ́ àdúrà mi;+Gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún ìrànlọ́wọ́. Dá mi lóhùn nínú òtítọ́ rẹ àti òdodo rẹ. 2 Má ṣe bá ìránṣẹ́ rẹ ṣẹjọ́,Nítorí kò sí alààyè kankan tó lè jẹ́ olódodo níwájú rẹ.+