Dáníẹ́lì 4:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Kò ka gbogbo àwọn tó ń gbé ayé sí nǹkan kan, ohun tó bá sì wù ú ló ń ṣe láàárín àwọn ọmọ ogun ọ̀run àti àwọn tó ń gbé ayé. Kò sí ẹni tó lè dá a dúró*+ tàbí kó sọ fún un pé, ‘Kí lo ṣe yìí?’+ Róòmù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ta ni ọ́, ìwọ èèyàn, tí o fi ń gbó Ọlọ́run lẹ́nu?+ Ṣé ohun tí wọ́n mọ máa ń sọ fún ẹni tó mọ ọ́n pé: “Kí ló dé tí o fi mọ mí báyìí?”+
35 Kò ka gbogbo àwọn tó ń gbé ayé sí nǹkan kan, ohun tó bá sì wù ú ló ń ṣe láàárín àwọn ọmọ ogun ọ̀run àti àwọn tó ń gbé ayé. Kò sí ẹni tó lè dá a dúró*+ tàbí kó sọ fún un pé, ‘Kí lo ṣe yìí?’+
20 Ta ni ọ́, ìwọ èèyàn, tí o fi ń gbó Ọlọ́run lẹ́nu?+ Ṣé ohun tí wọ́n mọ máa ń sọ fún ẹni tó mọ ọ́n pé: “Kí ló dé tí o fi mọ mí báyìí?”+