Jóòbù 26:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ó fi agbára rẹ̀ ru òkun sókè,+Ó sì fi òye rẹ̀ fọ́ ẹran ńlá inú òkun* sí wẹ́wẹ́.+