Àìsáyà 45:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó mà ṣe fún ẹni tó ń bá Aṣẹ̀dá rẹ̀* fa nǹkan* o,Torí ó dà bí àfọ́kù ìkòkò lásánLáàárín àwọn àfọ́kù ìkòkò míì tó wà nílẹ̀! Ṣé ó yẹ kí amọ̀ sọ fún Amọ̀kòkò* pé: “Kí lò ń mọ?”+ Àbí ó yẹ kí iṣẹ́ rẹ sọ pé: “Kò ní ọwọ́”?* Róòmù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ta ni ọ́, ìwọ èèyàn, tí o fi ń gbó Ọlọ́run lẹ́nu?+ Ṣé ohun tí wọ́n mọ máa ń sọ fún ẹni tó mọ ọ́n pé: “Kí ló dé tí o fi mọ mí báyìí?”+
9 Ó mà ṣe fún ẹni tó ń bá Aṣẹ̀dá rẹ̀* fa nǹkan* o,Torí ó dà bí àfọ́kù ìkòkò lásánLáàárín àwọn àfọ́kù ìkòkò míì tó wà nílẹ̀! Ṣé ó yẹ kí amọ̀ sọ fún Amọ̀kòkò* pé: “Kí lò ń mọ?”+ Àbí ó yẹ kí iṣẹ́ rẹ sọ pé: “Kò ní ọwọ́”?*
20 Ta ni ọ́, ìwọ èèyàn, tí o fi ń gbó Ọlọ́run lẹ́nu?+ Ṣé ohun tí wọ́n mọ máa ń sọ fún ẹni tó mọ ọ́n pé: “Kí ló dé tí o fi mọ mí báyìí?”+