Sáàmù 91:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Yóò ké pè mí, màá sì dá a lóhùn.+ Màá dúró tì í nígbà wàhálà.+ Màá gbà á sílẹ̀, màá sì ṣe é lógo. Míkà 7:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ ní tèmi, èmi yóò máa retí Jèhófà.+ Màá dúró* de Ọlọ́run ìgbàlà mi.+ Ọlọ́run mi yóò gbọ́ mi.+