Jẹ́nẹ́sísì 6:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Ní tèmi, màá mú kí ìkún omi + bo ayé kí n lè run gbogbo ẹran ara tó ní ẹ̀mí* lábẹ́ ọ̀run. Gbogbo ohun tó wà ní ayé ló máa pa run.+
17 “Ní tèmi, màá mú kí ìkún omi + bo ayé kí n lè run gbogbo ẹran ara tó ní ẹ̀mí* lábẹ́ ọ̀run. Gbogbo ohun tó wà ní ayé ló máa pa run.+