Sáàmù 107:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Wọ́n ń rìn tàgétàgé, wọ́n sì ń ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́ bí ọ̀mùtí,Gbogbo ọgbọ́n tí wọ́n ní já sí pàbó.+