-
Jóòbù 33:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Wò ó! Bákan náà ni èmi àti ìwọ rí níwájú Ọlọ́run tòótọ́;
Amọ̀ ni ó fi mọ+ èmi náà.
7 Torí náà, má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù mi bà ọ́ rárá,
Má sì jẹ́ kí jìnnìjìnnì bò ọ́ mọ́lẹ̀ nítorí mi.
-