28 Ẹ má ṣe jẹ́ kí èyí yà yín lẹ́nu, torí wákàtí náà ń bọ̀, tí gbogbo àwọn tó wà nínú ibojì ìrántí máa gbọ́ ohùn rẹ̀,+29 tí wọ́n á sì jáde wá, àwọn tó ṣe ohun rere sí àjíǹde ìyè, àwọn tó sọ ohun burúkú dàṣà sí àjíǹde ìdájọ́.+
35 Àwọn obìnrin rí àwọn òkú wọn gbà nípa àjíǹde,+ àmọ́ wọ́n dá àwọn ọkùnrin míì lóró torí pé wọn ò gbà kí wọ́n tú àwọn sílẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà, kí ọwọ́ wọn lè tẹ àjíǹde tó dáa jù.