-
Jóòbù 13:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ohun tí ẹ mọ̀ ni èmi náà mọ̀;
Mi ò kéré sí yín.
-
-
Jóòbù 16:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Mo ti gbọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan báyìí rí.
Olùtùnú tó ń dani láàmú ni gbogbo yín!+
-