Jóòbù 22:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ṣé o máa gba ọ̀nà àtijọ́Tí àwọn èèyàn burúkú rìn,16 Àwọn èèyàn tí a yára mú lọ,* kí àkókò wọn tó pé,Tí àkúnya omi* gbé ìpìlẹ̀ wọn lọ?+
15 Ṣé o máa gba ọ̀nà àtijọ́Tí àwọn èèyàn burúkú rìn,16 Àwọn èèyàn tí a yára mú lọ,* kí àkókò wọn tó pé,Tí àkúnya omi* gbé ìpìlẹ̀ wọn lọ?+