Jóòbù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n sì jókòó sílẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ fún ọ̀sán méje àti òru méje. Ẹnì kankan ò bá a sọ̀rọ̀, torí wọ́n rí i pé ìrora rẹ̀ pọ̀ gan-an.+
13 Wọ́n sì jókòó sílẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ fún ọ̀sán méje àti òru méje. Ẹnì kankan ò bá a sọ̀rọ̀, torí wọ́n rí i pé ìrora rẹ̀ pọ̀ gan-an.+