Sáàmù 22:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n ya ẹnu wọn sí mi,+Bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù, tó sì ń fa ẹran ya.+