-
Sáàmù 35:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àmọ́ nígbà tí mo kọsẹ̀, inú wọn dùn, wọ́n sì kóra jọ;
Wọ́n kóra jọ láti pa mí ní ibi tí wọ́n lúgọ sí dè mí;
Wọ́n ya mí sí wẹ́wẹ́, wọn ò sì dákẹ́ ọ̀rọ̀ ìbàjẹ́.
-