Sáàmù 27:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Má fi mí lé ọwọ́ àwọn elénìní mi,*+Nítorí pé àwọn ẹlẹ́rìí èké ti dìde sí mi,+Wọ́n sì ń halẹ̀ pé àwọn máa ṣe mí léṣe.
12 Má fi mí lé ọwọ́ àwọn elénìní mi,*+Nítorí pé àwọn ẹlẹ́rìí èké ti dìde sí mi,+Wọ́n sì ń halẹ̀ pé àwọn máa ṣe mí léṣe.