1 Àwọn Ọba 21:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Bí Áhábù ṣe gbọ́ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, ó fa ẹ̀wù ara rẹ̀ ya, ó sì gbé aṣọ ọ̀fọ̀* wọ̀; ó gbààwẹ̀, ó ń sùn lórí aṣọ ọ̀fọ̀,* ó sì ń rìn kiri nínú ìbànújẹ́. 2 Àwọn Ọba 6:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Bí ọba ṣe gbọ́ ọ̀rọ̀ obìnrin náà, ó fa aṣọ rẹ̀ ya.+ Nígbà tó sì ń kọjá lọ lórí ògiri, àwọn èèyàn rí i pé ó wọ aṣọ ọ̀fọ̀* sí abẹ́ aṣọ* rẹ̀.
27 Bí Áhábù ṣe gbọ́ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, ó fa ẹ̀wù ara rẹ̀ ya, ó sì gbé aṣọ ọ̀fọ̀* wọ̀; ó gbààwẹ̀, ó ń sùn lórí aṣọ ọ̀fọ̀,* ó sì ń rìn kiri nínú ìbànújẹ́.
30 Bí ọba ṣe gbọ́ ọ̀rọ̀ obìnrin náà, ó fa aṣọ rẹ̀ ya.+ Nígbà tó sì ń kọjá lọ lórí ògiri, àwọn èèyàn rí i pé ó wọ aṣọ ọ̀fọ̀* sí abẹ́ aṣọ* rẹ̀.