Sáàmù 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àárẹ̀ ti mú mi nítorí ẹ̀dùn ọkàn mi;+Láti òru mọ́jú ni omijé mi ń rin ibùsùn mi gbingbin;*Ẹkún mi ti fi omi kún àga tìmùtìmù mi.+ Sáàmù 31:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà, torí mo wà nínú ìdààmú. Ìrora ti sọ ojú mi di bàìbàì,+ àárẹ̀ sì ti bá gbogbo ara mi.*+ Ìdárò 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni mo ṣe ń sunkún;+ omijé sì ń dà lójú mi. Nítorí ẹni tó lè tù mí nínú tàbí tó lè tù mí* lára ti jìnnà réré sí mi. Àwọn ọmọ mi kò nírètí, nítorí ọ̀tá ti borí.
6 Àárẹ̀ ti mú mi nítorí ẹ̀dùn ọkàn mi;+Láti òru mọ́jú ni omijé mi ń rin ibùsùn mi gbingbin;*Ẹkún mi ti fi omi kún àga tìmùtìmù mi.+
9 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà, torí mo wà nínú ìdààmú. Ìrora ti sọ ojú mi di bàìbàì,+ àárẹ̀ sì ti bá gbogbo ara mi.*+
16 Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni mo ṣe ń sunkún;+ omijé sì ń dà lójú mi. Nítorí ẹni tó lè tù mí nínú tàbí tó lè tù mí* lára ti jìnnà réré sí mi. Àwọn ọmọ mi kò nírètí, nítorí ọ̀tá ti borí.