Sáàmù 88:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí pé wàhálà ti kún ọkàn* mi,+Ẹ̀mí mi sì ti dé ẹnu Isà Òkú.*+ 4 Wọ́n ti kà mí mọ́ àwọn tó ń lọ sínú kòtò;*+Mo ti di ẹni tí kò lè ṣe nǹkan kan,*+ Àìsáyà 38:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Mo sọ pé: “Ní àárín ọjọ́ ayé mi,Mo gbọ́dọ̀ wọnú àwọn ẹnubodè Isà Òkú.* A máa fi àwọn ọdún mi tó kù dù mí.”
3 Nítorí pé wàhálà ti kún ọkàn* mi,+Ẹ̀mí mi sì ti dé ẹnu Isà Òkú.*+ 4 Wọ́n ti kà mí mọ́ àwọn tó ń lọ sínú kòtò;*+Mo ti di ẹni tí kò lè ṣe nǹkan kan,*+ Àìsáyà 38:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Mo sọ pé: “Ní àárín ọjọ́ ayé mi,Mo gbọ́dọ̀ wọnú àwọn ẹnubodè Isà Òkú.* A máa fi àwọn ọdún mi tó kù dù mí.”
10 Mo sọ pé: “Ní àárín ọjọ́ ayé mi,Mo gbọ́dọ̀ wọnú àwọn ẹnubodè Isà Òkú.* A máa fi àwọn ọdún mi tó kù dù mí.”