Sáàmù 35:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run fi mí ṣẹ̀sín,*Wọ́n ń wa eyín wọn pọ̀ sí mi.+ Hébérù 11:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àní, àdánwò tí àwọn míì kojú ni pé wọ́n fi wọ́n ṣẹlẹ́yà, wọ́n sì nà wọ́n lẹ́gba, kódà ó jùyẹn lọ, wọ́n fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ dè wọ́n,+ wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n.+
36 Àní, àdánwò tí àwọn míì kojú ni pé wọ́n fi wọ́n ṣẹlẹ́yà, wọ́n sì nà wọ́n lẹ́gba, kódà ó jùyẹn lọ, wọ́n fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ dè wọ́n,+ wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n.+