-
Sáàmù 24:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ta ló lè gun orí òkè Jèhófà,+
Ta ló sì lè dúró ní ibi mímọ́ rẹ̀?
-
-
Sáàmù 84:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Wọ́n á máa ti inú agbára bọ́ sínú agbára;+
Kálukú wọn ń wá síwájú Ọlọ́run ní Síónì.
-