- 
	                        
            
            Jóòbù 14:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        19 Bí omi ṣe ń mú kí òkúta yìnrìn, Tí ọ̀gbàrá rẹ̀ sì ń wọ́ iyẹ̀pẹ̀ ilẹ̀. Bẹ́ẹ̀ lo ṣe sọ ìrètí ẹni kíkú dòfo. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jóòbù 19:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        10 Ó wó mi lulẹ̀ yí ká títí mo fi ṣègbé; Ó sì fa ìrètí mi tu bí igi. 
 
-