ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 24:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Kí o sì sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ẹnikẹ́ni bá sọ̀rọ̀ òdì sí Ọlọ́run rẹ̀, yóò jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀. 16 Torí náà, ẹ gbọ́dọ̀ pa ẹni tó bá tàbùkù sí orúkọ Jèhófà.+ Gbogbo àpéjọ náà gbọ́dọ̀ sọ ọ́ lókùúta. Ì báà jẹ́ àjèjì tàbí ọmọ ìbílẹ̀ ló tàbùkù sí Orúkọ náà, ṣe ni kí ẹ pa á.

  • Jóòbù 1:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àmọ́, kí nǹkan lè yí pa dà, na ọwọ́ rẹ, kí o sì kọ lu gbogbo ohun tó ní, ó dájú pé ó máa bú ọ níṣojú rẹ gan-an.” 12 Jèhófà wá sọ fún Sátánì pé: “Wò ó! Gbogbo ohun tó ní wà ní ọwọ́ rẹ.* Àmọ́, o ò gbọ́dọ̀ fọwọ́ kan ọkùnrin náà fúnra rẹ̀!” Ni Sátánì bá jáde kúrò níwájú* Jèhófà.+

  • Ìfihàn 12:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Mo gbọ́ tí ohùn kan ké jáde ní ọ̀run pé:

      “Ní báyìí, ìgbàlà+ àti agbára dé àti Ìjọba Ọlọ́run wa+ pẹ̀lú àṣẹ Kristi rẹ̀, torí pé a ti ju ẹni tó ń fẹ̀sùn kan àwọn ará wa sísàlẹ̀, ẹni tó ń fẹ̀sùn kàn wọ́n tọ̀sántòru níwájú Ọlọ́run wa!+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́