-
Jóòbù 5:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ẹni tí ebi ń pa jẹ ohun tó kórè,
Àárín àwọn ẹ̀gún pàápàá ló ti mú un,
Wọ́n dẹkùn mú àwọn ohun ìní wọn.
-
-
Jóòbù 22:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ṣé kì í ṣe torí pé ìwà burúkú rẹ pọ̀ jù ni,
Tí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ ò sì lópin?+
-