Jóòbù 11:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ ojú àwọn ẹni burúkú ò ní ríran mọ́;Wọn ò sì ní ríbi sá lọ,Ikú* nìkan ló sì máa jẹ́ ìrètí wọn.”+
20 Àmọ́ ojú àwọn ẹni burúkú ò ní ríran mọ́;Wọn ò sì ní ríbi sá lọ,Ikú* nìkan ló sì máa jẹ́ ìrètí wọn.”+