Lúùkù 18:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ṣé kò wá dájú pé Ọlọ́run máa mú kí a dájọ́ bó ṣe tọ́ fún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ tí wọ́n ń ké pè é tọ̀sántòru,+ bó ṣe ń ní sùúrù fún wọn?+
7 Ṣé kò wá dájú pé Ọlọ́run máa mú kí a dájọ́ bó ṣe tọ́ fún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ tí wọ́n ń ké pè é tọ̀sántòru,+ bó ṣe ń ní sùúrù fún wọn?+