Jóòbù 30:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Awọ ara mi ti dúdú, ó sì ti re dà nù;+Ooru* ti mú kí egungun mi gbóná. Sáàmù 102:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí bí mo ṣe ń kérora gidigidi,+Egungun mi ti lẹ̀ mọ́ ẹran ara mi.+